Fẹ́mi Adéṣínà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Femi Adesina)

Fẹ́mi Adéṣínà jẹ̀ ọ̀kan lára akọ̀wé ìròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,àti ọ̀gá àgbà agbani nímọ̀ràn lórí ọ̀rọ̀ ìròyìn àti afẹ́fẹ́ lábẹ́ ìjọba Ààrẹ Muhammadu Buhari[1]

Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọ̀gbẹ́ni Fẹ́mi Adéṣínà lọsí ilé ẹ̀kọ́ gíga Fásitì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ti Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun,bakan naa ó. tún lọ sí ilé èkọ́ ìmọ̀ ìṣòwò ní ìlú Èkó.

Iṣẹ́ẹ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọ̀gbẹ́ni Fẹ́mi Adéṣína yan iṣẹ́ akọ̀wé ìròyìn láàyò,óbẹ́rẹ́ iṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ti Ìpínlẹ̀ Èkó lórí ìkanì radio lagos nígbà tí ó ṣe ódarapọ́ mọ́ ẹgbẹ́ oníròyìn fángààdì,óṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́bí akọ̀wé ìròyìn fángààdì àti ìwé ìròyìn national Concord,lẹ́yìn àkókò díẹ̀ odarapọ mọ àjọ oníròyìn sun (the sun newspaper) ibẹ̀ lótidi ọ̀gá àgbà olóòtu. òṣìṣẹ́ kára ni ọ̀gbẹ́ni Fẹ́mi Adéṣínà èyí jẹko di aarẹ awon olootu agba fun ọdun meji lẹyin eyi otun di aarẹ gbogbo oniroyin ilẹ naijiria,nitóri iṣẹ ribiribi toti ṣe lagbo iroyin Aarẹ orilẹ ede naijiria Muhammadu Buhari fun lanfaani lati di ọga agba agbaninimọran pataki (special advisal)lorii media and publicity ni ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹ́jọ ẹgbàáọdún ólé mẹ́ẹ̀dógún-ún(31/08/2015).

Àmì ẹ̀yẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nigeria media merit award fun ní àmìn ẹ̀yẹ olóòtú àgbà ti ọdún 2007

  1. "About Femi Adesina: Nigerian journalist - Biography, Facts, Career, Wiki, Life". peoplepill.com. 2015-08-31. Retrieved 2021-09-23.