Femi Falana
Ìrísí
Femi Falana | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 30 December 1958 Lagos State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Lawyer |
Olólùfẹ́ | Funmi Falana |
Àwọn ọmọ | 1 |
Fẹ́mi Fálànà SAN (Senior Advocate of Nigeria) Jẹ́ agbẹjọ́rò àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn ọmọ orílẹ̀ èdè̀ Nàìjíríà tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹẹ̀dógbọ̀n Oṣu Kejìlá, ọdún 1958.(30 December, 1958[citation needed]).[1] Ó díje dupò Gómìnà ní ìpínl̀ẹ Èkìtì ní ọdún 2007 ṣùgbọ́n ó pàdánù ìbò náà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú NCP (National Conscience Party) tí ó ti fìgbà kan jẹ́ Alága ẹgbẹ́ náà jákè-jádò Nàìjíríà ní ọdún 2011..[2] Bákan náà, òun ni bàbá fún ọ̀kọrin, adẹ́rìín pòṣónú àti òṣèré orí ìtàgé tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Falz.[3] Fẹ́mi jẹ́ ọkọ fún arábìnrin Fúnmi Fálànà tí òun náà tún jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn ní orílẹ̀ èd̀e Nàìjíríà.[4]
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Femi Falana". informationng.com. Retrieved December 1, 2015.
- ↑ "Femi Falana". nigerianbiography.com. Archived from the original on December 8, 2015. Retrieved December 1, 2015.
- ↑ "My wife didn't like our son's music career –Femi Falana". The Punch. Archived from the original on August 24, 2015. Retrieved December 1, 2015.
- ↑ Simeon Ndaji (5 August 2012). "Femi Falana left me at the mercy of judges – Funmi,wife". Vanguard News. http://www.vanguardngr.com/2012/08/femi-falana-left-me-at-the-mercy-of-judges-funmiwife/. Retrieved 21 June 2016.