Jump to content

Femi Orenuga

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Femi Orenuga
Personal information
OrúkọKenny Oluwafemi Gbolahan Ademola Orenuga[1]
Ọjọ́ ìbí18 Oṣù Kẹta 1993 (1993-03-18) (ọmọ ọdún 31)[2]
Ibi ọjọ́ibíLewisham, England
Ìga5 ft 6 in (1.68 m)[2]
Playing positionMidfielder, winger
Youth career
2006–2008Southend United
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2008–2009Southend United0(0)
2009–2012Everton0(0)
2011Notts County (loan)2(0)
2012–2014AFC United8(1)
2014Whitehawk1(0)
2014Raufoss4(0)
2014Raufoss 23(0)
2015Gloucester City16(3)
2015Enfield Town
2015–2016Gloucester City7(0)
2016Wealdstone2(0)
2016Bedford Town (dual registration)
2016Corby Town
2016Farnborough3(0)
2016–2017Bedford Town15(3)
2018Peninsula Strikers5(2)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 5 March 2016.
† Appearances (Goals).

Kenny Oluwafemi Gbolahan Ademola " Femi " Orenuga (tí wọ́n bí ní 18 March 1993) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Gẹ́ẹ̀sì, tí ó ń gbá a ní ààrin-gbùngbùn.

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Orenuga tí wọ́n bí ní ìpínlẹ̀ Lewisham, ní London, darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Southend United ní ọdún 2006 lẹ́yìn tí ó wú ẹgbẹ́ náà lórí, nígbà tí aṣojú kan fà á kalẹ̀. [3] Kò pé tí ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ náà ni ó ṣe ìrànwọ́ fún Southend láti gba ife ẹ̀yẹ Norhanle ní orílẹ̀-èdè Denmark. Eléyìí tí ó mú kí àwọn ikọ̀ FC Copenhagen àtiBrøndby nífẹ̀ẹ́ sí i. Ó di agbábọ́ọ̀lù tó kéré jù lọ láti kópa fún ikọ̀ Southend United nígbà tí ó wọlé ní ìṣẹ́jú kẹ́tàléláàádọ́rùn-ún (93rd) ní ìjáwé-olúborí wọn lórí ikọ̀ Luton Town pẹ̀lú àmì-ayò mẹ́ta sí oókan nínú ìdíje FA Cup abala kejì, èyí tí ó wáyé ní keji ni 29, November 2008. [4] [5] [6]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "List of Players under Written Contract Registered Between 01/03/2010 and 31/03/2010" (PDF). The Football Association. Retrieved 2010-04-08. 
  2. 2.0 2.1 Hugman, Barry J., ed (2009). The PFA Footballers' Who's Who 2009–10. Mainstream Publishing. p. 318. ISBN 978-1-84596-474-0. 
  3. "Femi a record breaker". Southend United F.C.. 2008-12-01. Archived from the original on 2 December 2008. https://web.archive.org/web/20081202064308/http://www.southendunited.co.uk/page/NewsDetail/0%2C%2C10444~1472578%2C00.html. Retrieved 2008-12-01. 
  4. Femi Orenuga: Southend United’s youngest ever player on his time in Scandinavia and Australia englishplayersabroad.com
  5. "Southend 3-1 Luton". BBC Sport. 2008-11-29. http://newsimg.bbc.co.uk/sport1/hi/football/fa_cup/7741969.stm. Retrieved 2008-11-29. 
  6. "Southend vs Luton Town". Southend United F.C.. 2008-11-29. Archived from the original on 2 December 2008. https://web.archive.org/web/20081202131857/http://www.southendunited.co.uk/page/MatchReport/0%2C%2C10444~46783%2C00.html. Retrieved 2008-11-29.