Jump to content

Fig

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taxonomy not available for Ficus subg. Ficus; please create it automated assistant
Ficus carica – Common fig
Foliage and fruit drawn in 1771[1]
Ipò ìdasí
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/FicusFicus carica
Synonyms[2]

Fig jẹ́ èso tó ṣe é jẹ ti Ficus carica, ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà igi kékeré ti àwọn igi olódòdó láti ìdílé Moraceae, tó jẹ́ ìbílẹ̀ sí àwọn ènìyàn ní Mediterranean pẹ̀lú àwọn tó wà ní apá Ìwọ̀-oòrùn àti apá Gúúsù Asia. Wọ́n ti máa ń gbìn ín láti ìgbà àtijọ́, ó sì máa ń hù káàkiri àgbáyé.[3][4] Ficus carica jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà genus Ficus, ó sì ní ẹ̀yà ẹgbẹ̀rin (800) mìíràn.

Ìtàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Orúkọ yìí fig, tí wọ́n ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ ní èdè Gẹ̀ẹ́sì ní sẹ́ńtúrì kẹtàlá (13th century), jẹ yọ láti èdè Faransé ìgbaanì tó jẹ́ figue.[5] Èdè Ítálì náà ní fico, tó jẹ yọ látara Latin ficus. Orúkọ caprifig, Ficus caprificus Risso, náà jẹ yọ láti inú èdè Latin capro (goat) àti Gẹ̀ẹ́sì fig.[6]

Bí o ti rí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ficus carica jẹ́ igi gynodioecious, èyí tó jẹ́ igi tó fẹ́, tí ò sì ga púpọ̀, tó sì máa ń ga tó ìwọ̀n méje sí mẹ́wàá (7–10 m (23–33 ft)) ní gíga, pẹ̀lú èpo funfun. Ewé rẹ̀ tó 12–25 cm (4 12–10 in) ní gígùn, àti 10–18 cm (4–7 in) ní fífẹ̀, ó sì máa ń láwẹ́ lóríṣiríṣi.

Èso fig máa ń hù ní wọ̀ǹba, wọ́n sì ń pè é ní syconium, ètí tó ní òdòdó tó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìlà lára. Àwọn òdòdó kékeré rẹ̀ jọ kọ́ọ̀pù. Èso rẹ̀ máa ń ní kóró kan ṣoṣo, ní àárín rẹ̀.Ó ṣí sílẹ̀ ní àárín, kóró inú rẹ̀ sì tóbi. At maturity, these 'seeds' (actually single-seeded fruits) line the inside of each fig.[7]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1771 illustration from Trew, C.J., Plantae selectae quarum imagines ad exemplaria naturalia Londini, in hortis curiosorum nutrit, vol. 8: t. 73 (1771), drawing by G.D. Ehret
  2. "Search results — The Plant List". www.theplantlist.org. 
  3. The Fig: its History, Culture, and Curing, Gustavus A. Eisen, Washington, Govt. print. off., 1901
  4. RHS A-Z encyclopedia of garden plants. United Kingdom: Dorling Kindersley. 2008. pp. 1136. ISBN 978-1-4053-3296-5. 
  5. T.F. Hoad, The Concise Oxford Dictionary of English Etymology, Oxford University Press, 1986, page 171a.
  6. Condit, Ira J. (1947) The Fig; Chronica Botanica Co., Waltham, Massachusetts, USA.
  7. "Fig, Ficus carica". Purdue University: Horticulture & Landscape Architecture. Retrieved December 6, 2014.