Fio Fio
Ìrísí
Fio Fio jẹ́ ọbẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà tó wọ́pọ̀ láàárín apá Gúsù Ìlà-oòrùn, àwọn èròjà gbòógì ọbẹ̀ náà ni irúgbìn gínì àti ìṣù-kòkó.[1]
Orísun
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọbẹ fio fio náà jẹ́ ọbẹ̀ ìbílẹ̀ àwọn ará Ìpínlẹ̀ Ẹnúgu.[2]
Lápapọ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn èròjà tí wọ́n tún ń lò láti ṣe ọbẹ̀ fio fio ni efinrin, edé, epo pupa àti ùgbá. Wọ́n máa ń se irúgbìn gínì títí tó ma fi rọ̀ papọ̀ mọ́ achicha (ìṣù-kòkó lílọ̀).[3]
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí.
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Onyeakagbu, Adaobi (2021-05-10). "Fio Fio: How to prepare this spicy traditional Enugu dish". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-28.
- ↑ "How To Make Achicha And Fio-Fio". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-08-29. Retrieved 2022-06-28.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "How To Make Achicha And Fio-Fio". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-08-29. Retrieved 2022-06-28.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]