Àsìá ilẹ̀ Kìrìbátì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Flag of Kiribati)

Àsìá ilẹ̀ Kìrìbátì jẹ́ àsìá oŕilẹ̀-èdè. Ó nì àwọ́ pupa nì apá òkè pẹ̀lú eye góólù tí, ó fò lórí ìtànsán òòrùn pèlú àwọ̀ bọ́ọ̀lù ní apá ìsàlẹ̀ àti ìlà funfun tẹ́ẹ́rẹ́ mẹ̀ta. Àsìá náà jáde ní ọjọ́ kejìlá osù keje, ọdún 1979. Àwọ̀ funfun àti búúlù rẹ̀ túmọ̀ sí àwọn adágún odò ńlá tí o ́yíí óriĺẹ̀ - èdè náà kà. Eye tí ó ń fò lóríi ìtànsán òòrùn ná̀à túmọ̀ sí okun àti agbára àwọn adágún odò náà.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]