Florence Griffith-Joyner

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Florence Griffith Joyner
Florence Griffith Joyner2.jpg
Florence Griffith ní ọdún 1988
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́ Florence Delorez Griffith Joyner
Ọmọorílẹ̀-èdè American
Ọjọ́ìbí (1959-12-21)Oṣù Kejìlá 21, 1959
Los Angeles, California
Ọjọ́aláìsí September 21, 1998(1998-09-21) (ọmọ ọdún 38)
Mission Viejo, California
Height 1.69 m (5 ft 7 in)
Weight 59 kg (130 lb)
Sport
Orílẹ̀-èdè Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan United States
Erẹ́ìdárayá Running
Event(s) 100 meters, 200 meters
Retired 1988

Florence Delorez Griffith Joyner[1] (December 21, 1959 – September 21, 1998), bakanna bi Flo-Jo, jẹ́ eléré ìdárayá orí pápá ará Amẹ́ríkà. Wọ́n gbàá gẹ́gẹ́ bí "obìnrin tó yára jùlọ títí aye"[2][3][4] nítorí pé àwọn rẹ́kọ́ọ̀dù àgbáyé tó dà ní 1988 fún ìsáré 100 m àti 200 m kò tíì yipadà, kọ́ sí ti sí èni tó lè yípadà. Ó ṣe aláìsí lójijì lójú ọ̀run nítorí wárápá tó gbée ní ọdún 1998 nígbà tó jẹ́ ọmọ-ọdún 38. Yunifásítì Kalifóníà ní Los Angeles (UCLA) ló ti parí ẹ̀kọ́ rẹ̀.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]