Florence Kíkẹ́lọmọ Àjàyí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Florence Kíkẹ́lọmọ Àjàyí | ||
Ọjọ́ ìbí | 28 Oṣù Kẹrin 1977 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Àkúré, Nàìjíríà | ||
Ìga | 1.64 m (5 ft 5 in) | ||
Playing position | Ààbò | ||
Club information | |||
Current club | Pogoń Szczecin | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Koko Queens | |||
Rivers Angels | |||
Jegede Babes | |||
until 1999 | Pelican Stars | ||
1999–2001 | Niederkirchen | ||
2001–2004 | Police Machine | ||
2004–2008 | Bayelsa Queens | ||
2008–2010 | Tianjin Teda | ||
2011–2012 | Krka Novo Mesto | 7 | (0) |
2012–2013 | Pogoń Szczecin | ||
2013– | Dínamo Guadalajara | ||
National team | |||
1998–2008 | Ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà[A–1] | 19 | (2) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Florence Kíkẹ́lọmọ Àjàyí jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin tí ó wà nínú Ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà nígbà kan rí.[1] Ó ń gba bọ́ọ̀lù díje fún ìkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Dínamo Guadalajara ní orílẹ̀-èdè Spain alábala kejì.[2]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kíkẹ́lọmọ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá fún ìkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà pẹ̀lú Kókó Queens, Rivers Angels, Jagede Babes àti Pelican Stars ní abala ìdíje kejì tí obìnrin Nàìjíríà. Ó dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin, Niederkirchen ti orílẹ̀-èdè Germany lẹ́yìn tí ó kópa nínú àwọn Ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Nàìjíríà nínú ìdíje tí 1999 FIFA Women's World Cup. Ọdún méjì ló lò níbẹ̀. Lẹ́yìn èyí, ó padà sí Nàìjíríà, ó sìn gbá bọ́ọ̀lù jẹun fún Ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Police FC of Lagos àti Bayelsa Queen, kí ó tó tún fò fẹ̀rẹ̀ déró China, níbi tí ó ti dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin Tianjin Teda (women) lọ́dún 2008 tí ó sìn díje nínú ìdíje àgbábuta obìnrin wọn. Lẹ́yìn ọdún mẹ́wàá, ó dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin ZNK Krka ní Slovenia, Pogoń Szczecin ní Poland àti Dínamo Guadalajara ní Spain.[3][4][5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ WHY KIKELOMO AJAYI WILL NEVER PLAY FOR FALCONS AGAIN
- ↑ Dínamo Guadalajara signs Nigerian Florence Ajayi. FFemenino.es, 20 May 2013
- ↑ Statistics in the Slovenian Football Association's website
- ↑ "Kikelomo Ajayi Signs 2 Years Deal in Poland". Archived from the original on 19 January 2013. Retrieved 26 August 2012. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Letnia giełda transferowa". Archived from the original on 27 March 2016. Retrieved 26 August 2012. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)