Jump to content

Folúkẹ́ Dárámọ́lá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Folúkẹ́ Dárámọ́lá
Ọjọ́ìbíFebruary 15
Orílẹ̀-èdèNigeria
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1998-present
Àwọn ọmọ2

Folúkẹ́ Dárámọ́lá jẹ́ gbajúgbajà òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kejì (15th February) ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Bí Folúkẹ́ tí ń fakọyọ nínú sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá, bẹ́ẹ̀ náà ló dáńgájíá nínú tí èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ní sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa tí ó sìn pegedé. [1] [2] [3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. [/foluke-daramola-biography-profile-fabwoman/ "Foluke Daramola Biography - Profile"] Check |url= value (help). FabWoman | News, Style, Living Content For The Nigerian Woman. 2019-02-28. Retrieved 2019-12-24. 
  2. "5 things you need to know about actress". Pulse Nigeria. 2016-02-15. Retrieved 2019-12-24. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "FOLUKE DARAMOLA-SALAKO: I briefly left acting when it became monotonous - The Nation Newspaper". The Nation Newspaper (in Èdè Latini). 2019-11-10. Retrieved 2019-12-24.