Folake Olowofoyeku
Folake Olowofoyeku | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kẹ̀wá 1983 Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | The Folake |
Iṣẹ́ | Actress Musician |
Ìgbà iṣẹ́ | 2002–present |
Parents |
|
Àwọn olùbátan | Toby Foyeh (brother) |
Website | thefolake.com |
Folake Olowofowoyeku (bíi ni ọjọ́ kerìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1983)[1][2] jẹ́ òṣèré àti olórin ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[3] Ó kópa nínú eré Bob Hearts Abishola ní ọdún 2019.[4][5][6]
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Olowofowoyeku sí ìdílé Babatunji Olowofowoyeku àti Felicia Olowofowoyeku. Bàbá rẹ̀ jẹ́ olóṣèlú ní Nàìjíríà. Ó dàgbà sí ìlú Victoria Island ní ìpínlẹ̀ Èkó.[7] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Igbinedion Education Centre.[8] Ó gboyè nínú ìmò eré orí ìtàgé láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí City College of New York.[9][10]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní Off-Broadway theatre ní ìlú New York.[11] Olowofowoyeku tí kópa rán pé nínú àwọn eré 30 Rock, How to Get Away with Murder, Law & Order: Criminal Intent, Law & Order: Special Victims Unit, Modern Family, Westworld, àti White Collar. Olowofowoyeku kó ipa Minerva Jefferson nínú eré Death Race 2050 ní ọdún 2017. Ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2019, ó kópa Abishola nínú eré Bob Hearts Abishola.[12][13][14][15] Ó gboyè nínú ìmò audio engineering láti ọ̀dọ̀ Institute of Audio Research. Ó kópa nínú eré orin The Stars (Are Out Tonight) àti The Next Day ní ọdún 2013.[16][17][18]
Àwọn Ìtọ́kàsi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Bob Hearts Abishola Cast: Folake Olowofoyeku". Bob Hearts Abishola (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). CBS. Retrieved 25 September 2019.
- ↑ Bentley, Jean (23 September 2019). "Meet 'Bob Hearts Abishola' Star Folake Olowofoyeku" (in en). The Hollywood Reporter. https://www.hollywoodreporter.com/live-feed/meet-bob-hearts-abishola-star-folake-olowofoyeku-1241721.
- ↑ "Folake Olowofoyeku". Naluda. 23 January 2017. Archived from the original on 25 September 2019. https://web.archive.org/web/20190925102411/http://naluda.com/interviews/folake-olowofoyeku/.
- ↑ Goldberg, Lesley; Fienberg, Daniel; Lorre, Chuck (20 September 2019). "'TV's Top 5': NBC Streaming Plans Revealed; Plus Chuck Lorre on His Comedy Empire" (in en) (Audio interview, starts at 30:52). The Hollywood Reporter. https://www.hollywoodreporter.com/live-feed/tvs-top-5-chuck-lorre-big-bang-theory-streaming-deal-peacock-plans-revealed-1241168.
- ↑ Jones-Cooper, Brittany; Gardell, Billy; Olowofoyeku, Folake (9 September 2019). "Folake Olowofoyeku & Billy Gardell Speak On The CBS Series, "Bob ♥ Abishola"" (in en) (Video interview). BUILD Series. https://www.youtube.com/watch?v=cf9jjxXoiNU.
- ↑ Lorre, Chuck; Higgins, Al; Yashere, Gina; Gardell, Billy; Olowofoyeku, Folake; Frazier, Kevin (12 September 2019). "Bob Hearts Abishola - Creating a Sitcom About Immigrants" (in en) (Video interview). Paley Center for Media. https://www.youtube.com/watch?v=WgpAHLOTH0Q.
- ↑ Italie, Leanne (21 September 2019). "Folake Olowofoyeku hearts life in the television comedy lane". Chicago Tribune. Associated Press. https://www.chicagotribune.com/entertainment/tv/ct-ent-folake-olowofoyeku-bob-hearts-abishola-tv-20190921-g3howrs5hvfjhkn76w26vb7lfm-story.html.
- ↑ Saduwa, Patience (19 December 2016). ""I was excited on my first day on set"". The Nation. https://thenationonlineng.net/i-was-excited-on-my-first-day-on-set/.
- ↑ Folake Olowofoyeku - Bob Hearts Abishola Cast Member (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), retrieved 2020-07-24
- ↑ Barron, Rob (February 2017). "From Campus Stages to the 'Big Time'". Alumnus (City College of New York Alumni). Archived from the original on 2019-09-25. https://web.archive.org/web/20190925102405/https://ccnyalumni.org/alumnus/feb2017/4.html.
- ↑ Frieman, Richie (6 January 2017). "Folake Olowofoyeku". PensEyeView. Archived from the original on 11 November 2020. https://web.archive.org/web/20201111004625/http://www.penseyeviewnew.com/pev/2017/01/06/folake-olowofoyeku/.
- ↑ Framke, Caroline (23 September 2019). "TV Review: ‘Bob Hearts Abishola’ From Chuck Lorre" (in en). Variety. https://variety.com/2019/tv/news/bob-hearts-abishola-chuck-lorre-gina-yashere-1203346210/.
- ↑ Dowling, Amber (7 June 2019). "From economics student to actor, Folake Olowofoyeku may be this season’s break-out star" (Includes video interview). The Loop. https://www.theloop.ca/from-economics-student-to-actor-folake-olowofoyeku-may-be-this-seasons-break-out-star/.
- ↑ Udodiong, Inemesit (17 May 2019). "Folake Olowofoyeku: Nigerian actress plays lead role in new CBS show - here's why this is such a big deal". Pulse Nigeria. https://www.pulse.ng/bi/lifestyle/folake-olowofoyeku-nigerian-actress-plays-lead-role-in-new-cbs-show-heres-why-this-is/nx5fvsk.
- ↑ Ray, Rachel; Gardell, Bill; Olowofoyeku, Folake (30 September 2019). "Bob Hearts Abishola Star Folake Olowofoyeku On Growing Up As The Youngest of 20 Children" (Video interview). Rachael Ray. https://www.rachaelrayshow.com/video/bob-hearts-abishola-star-folake-olowofoyeku-on-growing-up-as-the-youngest-of-20-children.
- ↑ Hewitt, Zoey; Olowofoyeku, Folake (7 December 2016). "Folake Olowofoyeku Interview" (in en) (Video interview). AfterBuzz TV. https://www.youtube.com/watch?v=eRB5Yj_Qtqk.
- ↑ Bowie, David (26 February 2013). "David Bowie - The Stars (Are Out Tonight) (Official Video)" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Bowie, David (8 May 2013). "David Bowie - The Next Day (Explicit)" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).