Francisca Oboh Ikuenobe
Ìrísí
Francisca E. Oboh Ikuenobe | |
---|---|
Ìbí | Nigeria |
Ibùgbé | US |
Pápá | Geology, Palynology, Stratigraphy |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Missouri University of Science and Technology |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Cambridge |
Francisca Oboh-Ikuenobe jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ti Ẹ̀ka-ìmọ̀ nípa ayé is a (geology) ọmọ Ubiaja ní ìjọba-ìbílẹ̀ Esan South East Local Government ti Ìpínlẹ̀ Ẹdó.[1] Ìmọ̀ ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ni palynology àti sedimentology,[2] bẹ́ẹ̀ náà ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ni ẹ̀ká-ẹ̀kọ́ Geosciences and Geological and Petroleum and Engineering, bẹ́ẹ̀ náà ó jẹ́ igbakeji Ọ̀gá Ẹ̀ka-ìmọ̀ ẹ̀kọ́, (Associate Dean of Academic Affairs in the College of Engineering and Computing), tí yunifásítì Missouri University of Science and Technology.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Dr. Francisca Oboh-Ikuenobe". Voices of Edo Women. Archived from the original on 29 May 2014. Retrieved 29 May 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Francisca Oboh-Ikuenobe". LinkedIn. Retrieved 29 May 2014.
- ↑ "Francisca E. Oboh-Ikuenobe". Missouri University of Science and Technology. Archived from the original on 17 August 2021. Retrieved 29 May 2014.