Fred Amugi
Fred Nii Amugi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kọkànlá 1948 Accra, Ghana |
Iṣẹ́ | Actor, singer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1970–present |
Gbajúmọ̀ fún | Beasts of No Nation, The Cursed Ones, Holby City |
Awards | Accra International Film Festival, best actor 1994. Order of the Volta 2008, Golden movie awards 2016 |
Fred Nii Amugi (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kọkànlá ọdún 1948) jẹ́ àgbà ọ̀jẹ̀ òṣèré ti orílẹ̀-èdè Ghana tó gbajúmọ̀ fún àwọn ẹ̀dá-ìtàn tó ṣe nínú àwọn fíìmù bí i Holby City, Beasts of No Nation àti The Cursed Ones.[1][2][3][4] Ó di ìlú-mọ̀ọ́ká lẹ́yìn tó kópa nínú fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ní ọdún 1985 , èyí tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Opinto".
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Fred Amugi sí ìlú Teshie, Accra, ní Ghana, ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kọkànlá ọdún 1948. Ó lọ sí ilé-ìwẹ́ Broaks School. Lẹ́yìn náà ni ó lọ Takoradi Senior High School àti Nungua Senior High school. Ó darapọ̀ mọ́ iṣẹ́ ìlú fún ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n, ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i Olùdarí Supply ní Ministry of Finance ti Ghana.[5]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Amugi bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ fíìmù ṣíṣe ní ọdún 1970 pẹ̀lú àwọn erẹ́-oníṣe lóríṣiríṣi títí wọ ọdún 1985 nígbà tí ó ṣàfihàn nínú fíìmù rẹ̀ àkọ́kọ́ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Opinto". Fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán yìí ló mu di ìlú-mọ̀ọ́ká.[6]
Amugi ti ṣàfihàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù , ó sì ti ṣe oríṣiríṣi ẹ̀dá-ìtàn nínú àọn fíìmù bí i, Shoe Shine Boy (2013), Nyame Bekyere 1&2 (2015), Menua Paa Nie (2016), Housekeepers (2016) àti bẹ́ẹ̀ béẹ̀ lọ. Iṣẹ́ rẹ̀ àkọ́kọ́ tó ní ṣe pẹ̀lú orílẹ̀-èdẹ̀ mìíràn wáyé ní ọdún 2005, nígbà tí ó ṣe ẹ̀dá-ìtàn Kwame Attakora nínú eré-oníṣe ti BBC Holby City.[7][8] [9] Lẹ́yìn náà, ó kópa nínú fíìmù Netflix ti ọdún 2015, ìyẹn Beasts of No Nation èyí tí ó ṣe ẹ̀dá-ìtàn "Pastor".[10][11][12] Amugi ṣe ẹ̀dá-ìtàn Pastor Uchebo nínú fíìmù "The Cursed Ones", èyí tó gba àmì-ẹ̀yẹ ìlú Britain ní ọdún 2015.[13][14]
Àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fíìmù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Film | Role | Notes |
---|---|---|---|
1989 | African Timber | ||
1992 | The Other Side of the Rich | Stephen Kodua | |
2001 | The Scent of Danger | ||
2004 | Welcome Home | Black Doctor | |
2005 | Madam Pink | Police Chief | |
2007 | In the Eyes of My Husband | Nana Boateng | Direct-to-video |
2009 | Punctured Hope | Togbe | |
2011 | The Destiny of Lesser Animals[15] | Oscar Darko | |
2015 | Pieces of Me | Board Member | Direct-to-video |
The Impossible | Completed | ||
Beasts of No Nation[16] | Pastor | ||
Chronicles of Odumkrom: The Headmaster | Kofi Bediako | ||
The Cursed Ones | Pastor Uchebo | ||
2016 | Beautiful Ruins[17] | ||
Housekeepers[18] | |||
2017 | Sala | ||
Keteke | Old Man | ||
The Hero Film | Mr. Boateng | ||
2018 | Lucky | Father | |
2019 | Bigman Wahala | Nana | |
2020 | Gold Coast Lounge | Adwene Mu Ti | |
Aloe Vera | Mr. Aloemele | ||
1st Kings | Nana Nyansa | Short film | |
Agadez | Imam | Short film | |
2021 | Borga | Priest | |
2022 | Terminus | Major Nuhu | Completed |
2023 | Nine | Witch Doctor | |
2024 | Evor | Mr. Amable | Drama |
Eré orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Film | Role | Notes |
---|---|---|---|
2005 | Holby City | Kwame Attakora | Episode: "Tuesday's Child" |
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Award | Category | Nominated work | Result |
---|---|---|---|---|
1994 | Accra International Film Festival | Best Actor | Àdàkọ:Win | |
2008 | Order of the Volta | Ghana National Award for Acting | Àdàkọ:Win | |
2016 | Ghana Movie Awards | Best Actor In Supporting Role | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |
Golden Movie Awards | Golden Supporting Actor in a Drama | The Cursed Ones[20] | Àdàkọ:Win | |
Golden Movie Awards | Golden Supporting Actor in a Drama | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Fred Nii Amugi". IMDb. Retrieved 27 October 2018.
- ↑ "Holby City". Genome BBC. Retrieved 27 October 2018.
- ↑ "See photos of aging veteran actor, Fred Amugi". Ameyaw Debrah. Archived from the original on 27 October 2018. Retrieved 27 October 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Fred Amugi sheds tears after receiving donation from Gloria Sarfo". Ghanaweb.com. 6 April 2018. Retrieved 27 October 2018.
- ↑ "Fred Amugi's Biography". sodasandpopcorn.com. Retrieved 27 October 2018.
- ↑ "Africa: Who is Fred Amugi?". allafrica.com. Retrieved 27 October 2018.
- ↑ "Tuesday's Girl". TV.com. Archived from the original on 28 October 2018. Retrieved 31 May 2018.
- ↑ "Full Cast & Crew". IMDb. Retrieved 27 October 2018.
- ↑ "Holby City: Tuesday's Child". digiguide.tv. Retrieved 27 October 2018.
- ↑ "Beasts of No Nation". IMDb. Retrieved 27 October 2018.
- ↑ "Beasts of No Nation". fandango.com. Retrieved 27 October 2018.
- ↑ "Cast: Beast of No Nation (2015)". wonderfulcinema.com. 30 April 2016. Retrieved 27 October 2018.
- ↑ "The Cursed Ones film". thecursedones.com. Archived from the original on 2017-07-31. Retrieved 2024-08-20.
- ↑ "The Cursed Ones – film – SensCritique". senscritique.com.
- ↑ "The Destiny of Lesser Animals Movie". destinyoflesseranimals.com.
- ↑ "Fred Amugi". Rotten Tomatoes.
- ↑ "BEAUTIFUL RUINS Starring John Dumelo and Christabel Ekeh Premieres on 18th March; Watch Trailer". 19 February 2016. Archived from the original on 9 October 2023. Retrieved 22 June 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Fred Amugi". 30 July 2018. Archived from the original on 12 April 2019. Retrieved 27 October 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Uju (25 November 2016). "Check Out The Full List Of Nominees For 2016 Ghana Movie Awards". Answers Africa. Archived from the original on 12 April 2019. Retrieved 27 October 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Winners @ the 2016 Golden Movie Awards". Ytainment. Retrieved 11 December 2021.
- ↑ "Video + Full List of Nominees for 2016 Golden Movie Awards Africa (GMAA)". Modern Ghana.