Jump to content

Frederic Fokejou

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Frederic Fokejou Tefot (ti a bi ni ọjọ keta Oṣu kejila ọdun 1979 ni Bafoussam, orile edè Cameroon ) jẹ agbẹru iwuwo ara orilẹ-ede Kamẹru . [1] O dije ni Olimpiiki Igba ooru 2012 ni iṣẹlẹ +105 kg .

  1. Empty citation (help)