Funke Abimbola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Funke Abimbola
MBE
Ọjọ́ìbíNigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaNewcastle University
Gbajúmọ̀ fúnGeneral Counsel, Legal Work and Public Service
Websitefunkeabimbola.com

Funke Abimbola MBE jẹ́ oníṣòwò tí orílé èdè Nàìjíríà àti agbẹ́jórò. Ó jẹ́ alágbàwí fún onírúurú nípa iṣẹ́ amòfin ní orílé èdè U.K.

Abimbola lọ sí Newcastle University láti lọ ní ìmọ nípa Òfin (láé).[1] Ó sí bí ọmọ ọkùnrin kan nígbà tí ó ń ba Campbell Hooper ṣíṣe

Ìbẹ̀rẹpẹ̀pẹ̀̀́ Ayé àti Ìwé kíkà rẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Abímbólá je ẹnikan tí ó tí ìdílé àwọn oníṣe ìṣẹ̀gun òyìnbó. Abimbola comes from a family of medical doctors.[2] ọ sí kàwé ni Burgess Hill Girls.[3] She did not study medicine because of her fear for "pains and blood" (algophobia and hemophobia). Ó gbà ìwé erí ati oyè nípa Ofin ni Newcastle University.[4] Ó wá sí Nàìjíríà ní àárín 1990 láti wá ṣe ììdánwò NigerianBar examination.[1] Ó bẹ́rẹ̀ sí ní bímọ nígbà tí ó di ọmọ ọdún méjìdínlógbọ̀n, ọ sí ń ṣíṣe fún Campbell Hooper.[1] Ní ọdún 2000, Ó dì agbẹjørò fún òrò Ilé (Ìn House Solicitor).[5]Ní ọdún 2012, bàbá rẹ̀ jáde láyé wọ́n sí ṣè ìwádìí pé ààrùn Jẹjẹrẹ ní o pá.[6][7]

Iṣé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Abímbólá jẹ́ Àgbà Agbejọ́rọ̀ tí o sí je aláwọ̀ dúdú fún ilé iṣé Roche's pharmaceutical operations ní orílé èdè UK, Ireland, Gibraltar àti Malta.[8] She qualified as a solicitor in-house in 2000.[5] Óò lọ sí orílè èdè Nàìjíríà láti lọ ṣé ìdánwò Nigerian Bar examination. Nígbà náà ló ń ṣíṣe fún F. O. Akinrele & Co.[7] Lẹyìn èyí ní ó padà sí UK láti orílè èdè Nàìjíría ní àárín ọdún 1990, Óò sì ṣíṣe pẹ̀lú Wembley Plc níbi tí ó ti di agbejoro fún àjọṣepọ̀ ìṣòwòb(Corporate Commercial Lawyer) lẹyìn ìgbà náà ní ó bá Campbell Hooper tí ó sí di Agbẹjọro (Solicitor).[7] Ní ọdún 2012,. Óò dara ọ mọ́ Roche UK, èyí tí ó sí wá ni ipò Oluṣàkóso Ìmọràn (managing Counsel) ni UK àti Ireland. Óò tún jẹ UK Data Protection Officer. Ní oṣù tí ó gbẹyin ọdún 2015, ó di General counsel àtí secretary fún ilé iṣé yẹn, ó sí gbà ìgbéraga lẹ́nu iṣé rẹ̀ tí ó fí di general counsel. Ní oṣù kínní ọdún 2017 ọ sí di head of financial compliance. Abímbólá jẹ́ alágbàwí tí ó ní agbára nípa iṣé onírúurú Ofin.[9] Gẹ́gẹ́ bí ẹnìkan tí ó jẹ́ agbọrọsọ gbangba ati oṣiṣẹ ofin, ó ti gba àmì ẹ̀yẹ fún iṣẹ́ tí ó ń ṣé takuntakun. Ní 2013, orúkọ rẹ̀ wá ní ìtẹ̀jáde tí wọn ń pè ní Diversity League Table tí ó sí wá láàárín àwọn agbéró aláwọ̀ dúdú. Ní 2014, en Yàn fún National Diversity Award, ní ọdún náà bákan náà ní wọn tún Yàn fún ae same 'the Law Society Excellence Awards. Ní ọdún 2015, ó gba Ẹ̀bùn àmì ẹ̀yẹ 'Positive Role Model Award'.[10] In 2010, she was appointed governor of Uxbridge College, London, on a four-year term.[11] Ó gba àmì ẹ̀yẹ'Point of Light' láti ọwọ́ Ààre UK ní oṣù kẹwa ọdún 2016, fún ipá onírúurú ní orílè èdè Uk. Ní ọdún 2017, Ọ gbà àmi ẹ̀ye M.B.E. (Member of the Order of the British Empire) láti Queen Elizabeth II fún iṣé oríṣi lórí iṣẹ́ òfin àti fún àwọn ọ̀dọ́.[12]

Ó gba Àmi tí wọn ń pè ní honorary doctor of lawa ní fásitì tí Hertfordshire ( University of Hertfordshire) ní oṣù kẹsán, ọdún 2019, èyí tí wọ́n fí ń rí àwọn oríṣìíríṣìí àwọn ọnà tí ó tí gbà lọ́wọ́ sí yálà ní iṣẹ́ ìfun tàbí ní tí àwùjọ.[13]

Àwọn Ẹbùn àti Àmì Ẹ̀yẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Class Category Awarding body
2015 Winner Positive Role Model (Gender) Award National Diversity Awards 2015
2015 Winner Career Woman of the Year Award Women4Africa
2015 Winner Outstanding Woman in Professional Services Precious Award
2015 Winner Inspiring Member of the Year Inclusive Network Awards
2015 Certificate of Merit British Citizen Awards 2015
2016 Winner Outstanding Diva of the year Divas of Colour
2016 Winner International Diva of the Year Divas of Colour
2016 Winner Best Public Speaker CA Awards by C. Hub Magazine
2016 Winner Best Non-fiction CA Awards by C. Hub Magazine
2016 Recognition Recognition award for outstanding achievements and contributions Women4Africa
2016 Point of Light Volunteers Award UK Prime Minister 2016
2017 M.B.E. (Member of the Order of the British Empire) For services to diversity in the legal profession and to young people Queen Elizabeth II
2019 L.L.D. (Honorary Doctor of Laws) For contributions to social and corporate diversity The University of Hertfordshire

Sources:[8][10][14]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 Eduardo Reyes. "Funke Abimbola". The Law Society Gazette. Archived from the original on 9 July 2018. Retrieved 29 June 2016. 
  2. "106 seconds with… Funke Abimbola, Managing Counsel for Roche UK, diversity champion, speaker and proud mother". 6th Sense. Retrieved 29 June 2016. 
  3. "Catching Up With 'Old Girl' Funke Abimbola". Burgess Hill Girls. Archived from the original on 3 October 2017. Retrieved 3 October 2017. 
  4. "General Counsel & Company Secretary (Roche UK)". aspiring solicitors. Archived from the original on 16 August 2016. Retrieved 30 June 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. 5.0 5.1 "Funke Abimbola". First100years. Retrieved 29 June 2016. 
  6. "Inspirational Woman: Funke Abimbola. Solicitor for one of the world's largest biotech companies". We are the City. Retrieved 29 June 2016. 
  7. 7.0 7.1 7.2 Ruxandra Iordache. "Careers counsel for aspiring lawyers: Roche's Funke Abimbola". Legal Business. Retrieved 29 June 2016. 
  8. 8.0 8.1 Women4Africa. "Funke Abimbola: Profile of an achiever". The Guardian. Retrieved 29 June 2016. 
  9. "INTERVIEW: FUNKE ABIMBOLA GENERAL COUNSEL AND COMPANY SECRETARY, ROCHE". Legal 500. Archived from the original on 9 July 2018. Retrieved 7 July 2016. 
  10. 10.0 10.1 "General Counsel & Company Secretary, Roche UK". Speakers4Schools. Archived from the original on 9 July 2018. Retrieved 7 July 2016. 
  11. IBB Solicitors. "Funke Abimbola appointed governor of Uxbridge College". Retrieved 8 July 2016. 
  12. "Nigeria’s Funke Abimbola honoured by Uk Prime Minister for championing diversity in the workplace". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-10-22. Retrieved 2022-05-23. 
  13. Ajumobi, Kemi (2022-04-01). "FUNKE ABIMBOLA (MBE), the diversity campaigner who dared and excelled". Businessday NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-23. 
  14. "Profile: Funke Abimbola-Akindolie MBE, a multi-award winning solicitor". Nairametrics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-12-07. Retrieved 2021-05-19.