Funmi Aragbaye
Ìrísí
Funmi Aragbaye | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | July 5, 1954 Ondo State, Nigeria Protectorate |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Veronica |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1983 - present |
Funmi Aragbaye (tí a bí ní ọjọ́ 5 oṣù 1954) jẹ́ olórin ìhìnrere ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,akọrin àti oníwàásù afẹ́fẹ́.[1][2] Ó fẹ́ Bola Aragbaye tí o ti di olóògbé,pẹ̀lú ọmọ mẹta.[3]
Àtòjọ àwọn orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Olorun Igbala (1983)
- Sioni ilu ayo' (1983)
- pin Rere (Good Portion)'
- Glory of God (Ogo Oluwa)
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Music Marketers Are Dubious--Funmi Aragbaiye". nigeriafilms.com. Archived from the original on 5 April 2015. Retrieved 15 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Marketers are dubious-Funmi Aragbaye". The Nigerian Voice. Retrieved 15 March 2015.
- ↑ "Funmi Aragbaye Biography: Age, Husband, Children & Net Worth - Famous Today" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-10-21. Retrieved 2023-10-28.