Jump to content

Funmi Jimoh

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Funmi Jimoh
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kàrún 1984 (1984-05-29) (ọmọ ọdún 40)
Seattle, Washington
Height1.73 metres (5 ft 8 in)
Weight59 kilograms (130 lb)
Sport
Orílẹ̀-èdèÀwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà
Achievements and titles
Personal best(s)Long Jump 6.96 m (2009)

Oluwafunmilayo Kemi Jimoh (tí a bí ní ọjọ́ ọ̀kàn-dín-lọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún, ọdún 1984, ní Seattle, Washington) [1] , tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Funmi Jimoh, jẹ́ olùfò gígùn (long jumper) ti Amẹ́ríkà, tí ó díje ní Òlímpíkì Ìgbà oòrùn ọdún 2008.

Jimoh díje fún 'Rice University'. Ní Rice, Jimoh díje nínú méjéèjì fífò gígùn àti àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ 'sprinting', gẹ́gẹ́ bí àwọn òdiwọ̀n ọgọ́run mítà.[2]



  1. eurosport.com https://www.eurosport.com/athletics/funmi-jimoh_prs159237/person.shtml. Retrieved 2023-04-30.  Missing or empty |title= (help)
  2. "Q&A: Funmi Jimoh". Archived from the original on 2007-06-04. Retrieved 2023-04-30.