Funsho Adeolu
Funsho Adeolu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ondo State, Nigeria | 9 Oṣù Kàrún 1968
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Oǹdó State University |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1976- till present |
Notable work | http://www.askmen.com/sex/erection.html and Zeroes (2010) |
Olólùfẹ́ | Victoria Adeolu |
Àwọn ọmọ | ọmọkunrin meji . |
Funsho Adeolu (tí a bí ní Ọjọ́ Kẹ̀sán-án Oṣu Kàrún ún, ọdún 1968) jẹ́ òṣèré sinimá-àgbéléwò, olùdarí àti olóòtú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà [1][2]
Ìgbé-ayé ni ìgbà èwe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Fúnnṣọ́ Adéolú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù karùn-ún ọdún 1968 ni ìpínlẹ̀ Oǹdó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó kàwé àkóbẹ̀rẹ̀ ní Baptist Academy. Ó kàwé gboyè gíga ni ifásitì ìpínlẹ̀ Oǹdó, Oǹdó State University. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1976. Ère àgbéléwò tó mú un gbajúmọ̀ ni "Countdown to Kusini" àti "Heroes and Zeroes" lọ́dún 1976. Láti ìgbà náà ló ti di ìlúmọ̀ọ́kà lágbo sinimá-àgbéléwò. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa àti èyí tí òun fúnra rẹ̀ tí kọ. Lára wọn ni; Ojú Àpá, Ẹyin Ọká, Jèsù Muṣhin, Àṣírí Owó, Ibojì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Kì í ṣe sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá nìkan ni Fúnṣọ Adéolú ti dáńtọ́, àìmọye sinimá àgbéléwò lédè Gẹ̀ẹ́sì náà lo tí kópa, lára wọn ni; Family Ties, Silenced, Things Fall Apart àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Ìgbé ayé tí ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O fẹ arabinrin Mrs. Victoria Adeolu won bí ọmọkunrin meji .[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "My wedding ring is my only fashion accessory –Funsho Adeolu". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2015-04-14. Retrieved 2019-02-13.
- ↑ RONKE KEHINDE and AUGUSTA EYIDE. "My wife is simple, homely... and I love it that way---Funsho Adeolu". nigeriafilms.com.
- ↑ "I tell my wife before I act romantic roles—Funsho Adeolu". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2015-04-14. Retrieved 2015-04-13. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)