Jump to content

Gani Adams

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Fáìlì:Ààrẹ Ọ̀nà Ààrẹ Ọ̀nà Kakaǹfò

Gani Adams
Ọjọ́ìbíOtunba Ganiyu Adams
30 Oṣù Kẹrin 1970 (1970-04-30) (ọmọ ọdún 54)
Arigidi-Akoko, Akoko North-West, Ondo State
Iléẹ̀kọ́ gígaLagos State University
Iṣẹ́ajìjàngbara
Ìgbà iṣẹ́1992–present
OrganizationOlokun Festival Foundation
MovementOodua Peoples Congress

Iba Gàníyù Adams t́i fi ìgbà kan jẹ́ olórí ẹgbẹ́ ọmọ Odùduwà tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí O.P.C, A bí Ọ̀túnba Ganiyu Adam ní (ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹrin ọdún 1970). Ó jẹ́ ajìjàngbara àti Ààrẹ Ọ̀nàkakaǹfò. [1]

Ìgbẹ́ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Gani Adams ni ọjọ́ kẹẹ̀dọgun oṣù kẹrin ọdún 1970, ní Arigidi-Akoko tí wọ́n pè ní Àkókò North-west local government,Ondo State ni òdé òní.

Gani Adams bẹ̀rẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ni Army Children's School, Otukpo, Ìpínlè Benue. Sùgbọ́n nítorí irú ìṣẹ́ bàbá rẹ, wọ́n kó lọ sí ìlú Eko níbi tí o ti parí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀bẹrẹ̀ ní Municipal Primary School ní SurulereÌpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 1980. Lẹ́yìn ẹ̀kọ́ alákọ̀bẹrẹ̀ rẹ̀, o tẹsìwàjú lọ sí Ansar-Ud-deen Secondary School, Randle Avenue, Surulere. Lẹ́yìn ẹ̀kọ́ girama ,ó lọ kọ́ nípa ṣíṣe àwọ́n ọ̀ṣọ́ ilé tí ó sì parí ní ọdún 1987.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Odunsi, Wale (2018-01-16). "Aare Ona Kakanfo: Why I chose Gani Adams out of 25 candidates - Alaafin of Oyo". Daily Post Nigeria. Retrieved 2018-07-20. 
  2. "PROFILE: From OPC leader to generalissimo of Yorubaland, the transformation of Gani Adams". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-10-17. Retrieved 2021-01-28.