Garcinia assamica

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taxonomy not available for Garcinia; please create it automated assistant
Garcinia assamica
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/GarciniaGarcinia assamica
J.Sarma, Shameer & N.Mohanan

Garcinia assamica je eya irúgbìn ti a sẹsẹ ri ni agbegbe Manas National Park, Assam.[1] O Jo nkan ti ko wọpọ ati wipe iwonba àwọn ènìyàn kekere lo mo.[2] Eya Titun yìí jé ìbátan sí Garcinia nigrolineata[2][3] ni tito ododo lori axillary short spikes; tito stamens lori convexdisc ati iye nomba pelu staminodes lori abo ododo ; sugbon iyato eleyii ati eyi to keyin ni pé,eyi to keyin maan ni awo ewe sí ofeefe ti ki se ofeefe exudate; abo ododo meji sí máàrún fascicled ni nodi tí o gbọdi sí solitary flowers; ovaries locular merin sí máàrún lori locular máàrún .[2]

Tun wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awọn Atọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Link ti ta[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Clusiaceae-stub