Garcinia humilis

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taxonomy not available for Garcinia; please create it automated assistant
Garcinia humilis
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/GarciniaGarcinia humilis

Garcinia humilis, ti a tun mo sí achachairú or achacha, je eso igi ti o kere ti o tun tan mo mangosteen. O maan Wu ni apa southern Amazon basin ni aarin agbègbè Bolivia, sugbon ni enu ijo meta yii,a gbin ni rẹpẹtẹ fun tita ni Burdekin, Australia. Eso yi se ipo keta ni ọdún 2012 ni àwardi Fruit Logistica Innovation Awards ti won se ni Berlin.[1]

Appearance[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Achacha je eso ti o dara lati wo loju,awo rè sí da gidi. Irisi re dàbí ti eyin,o sì to centimeter mefa sí mẹrin ni diameter. O ni awo pupa mọ osan ti o ba pọn. Eso kaffee ti o se pataki ni,sugbon eso yìí lè ní ju irúgbìn eyo kan lo.

Awọn Atokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Achacha honored at Fruit Logistica". freshplaza.com. Archived from the original on 2015-04-02. Retrieved 2015-03-07.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)