Jump to content

Georg Cantor

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Georg Cantor
Georg Cantor
ÌbíGeorg Ferdinand Ludwig Philipp Cantor
(1845-03-03)Oṣù Kẹta 3, 1845
Saint Petersburg, Russia
AláìsíJanuary 6, 1918(1918-01-06) (ọmọ ọdún 72)
Halle, Germany
IbùgbéRussia (1845–1856),
Germany (1856–1918)
PápáMathematics
Ilé-ẹ̀kọ́University of Halle
Ibi ẹ̀kọ́ETH Zurich, University of Berlin
Doctoral advisorErnst Kummer
Karl Weierstrass
Doctoral studentsAlfred Barneck
Ó gbajúmọ̀ fúnSet theory
Religious stanceLutheran

Georg Ferdinand Ludwig Philipp Cantor (pipe /ˈkʰæn-tɔ̝ː(ɚ)/ KANN-tor; German: /ɡ̥eˈɔʁk (ˈfɛʁdinant ˈluːtvɪç ˈfiːlɪp) ˈkʰantɔʁ/ (March 3 [O.S. February 19] 1845[1] – January 6, 1918) je onimo mathimatiiki ara Jemani to gbajumo gege bi oluda ero akojopo, to je ero ipilese ninu mathematiiki. Cantor sedasile pataki idojuko ikookan larin awon akojopo, o setumo awon akojopo alailopin ati awon akojopo agunrege, to si fihan pe awon nomba gidi "po lopolopo" ju awon nomba adaba lo. Looto, agbesiro Cantor so pe "ailopin awon ailopin" wa. O tumo awon nomba onikoko ati eleto ati isiro won. Ise Cantor se pataki nipa oye won, ohun gangan na si mo eyi.[2]




  1. Grattan-Guinness 2000, p. 351
  2. The biographical material in this article is mostly drawn from Dauben 1979. Grattan-Guinness 1971, and Purkert and Ilgauds 1985 are useful additional sources.