George Kunda

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
George Kunda

George Kunda (ojoibi February 26, 1956 ni Luanshya) je oloselu ara Zambia. Lowolowo Kunda ni Igbakeji Aare ile Sambia lati 2008 labe Aare Rupiah Banda.


References[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]