Gianna Angelopoulos-Daskalaki
Ìrísí
Gianna Angelopoulos-Daskalaki (abiso Gianna Daskalaki ni December 12, 1955 ni Heraklion, Crete) je Griiki obinrin onisowo.[1] Ohun lo je aare igbimo idu ati igbajo fun Awon Idije Olimpiki Igba Oru 2004 ni Athens, Greece. O je didaruko bi ikan ninu awon obinrin alagbara julo latowo iwe-iroyin Forbes.
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Mrs. Gianna Angelopoulos - Daskalaki". Xapital Link. Archived from the original on 2009-01-07. Retrieved 2008-07-12.