Gift Otuwe
Ìrísí
Gift Otuwe (2016–17 season) | |||
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Gift Ele Otuwe | ||
Ọjọ́ ìbí | 15 Oṣù Keje 1984 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Ìga | 1.65m | ||
Playing position | Midfielder, Striker | ||
Club information | |||
Current club | Bobruichanka Bobruisk | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Bayelsa Queens FC | |||
2012–2016 | FC Minsk (women) | 97 | (34) |
2017 | 1207 Antalya Spor | 10 | (0) |
2019-2020 | Neman Grodno (women) | 28 | (4) |
2021- | Bobruichanka Bobruisk | 23 | (13) |
National team | |||
Nigeria women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 4 June 2017. † Appearances (Goals). |
Gift Otuwe jẹ agbabọọlu lobinrin òrilẹ ede naigiria ti a bini 15, óṣu July ni ọdun 1984. Arabinrin naa ṣere fun Bobruichanka ni premier league Belarusia[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Gift kopa ninu Olympic 2004 ati Cup agbaye ni ọdun 2007 nibi ti arabinrin naa ti ṣe aṣoju apapọ team naigiria[4]