Jump to content

Gjorge Ivanov

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gjorge Ivanov
Ѓорге Иванов
President of Macedonia
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
12 May 2009
Alákóso ÀgbàNikola Gruevski
AsíwájúBranko Crvenkovski
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí2 Oṣù Kàrún 1960 (1960-05-02) (ọmọ ọdún 64)
Valandovo, Yugoslavia (now Macedonia)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent
(Àwọn) olólùfẹ́Maja Ivanova
ResidenceVila Vodno, Skopje
Signature

Gjorge Ivanov, tabi Ǵorge (Àdàkọ:Lang-mk, [ˈɟɔrɡɛ ˈivanɔf]; ojoibi 2 Osu Karun, 1960 ni Valandovo, SR Macedonia, Yugoslavia), ni Aare Orile-ede Olominira ile Makedonia lowolowo lati Osu Karun 2009.