Glafcos Clerides

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Glafcos Clerides
4th President of Cyprus
In office
28 February 1993 – 28 February 2003
AsíwájúGeorge Vasiliou
Arọ́pòTassos Papadopoulos
In office
23 July 1974 – 7 December 1974
AsíwájúNikos Sampson (acting)
Arọ́pòArchbishop Makarios III
1st President of the House of Representatives
In office
1960–1976
AsíwájúNew office
Arọ́pòTassos Papadopoulos
1st President of DISY
In office
1976–1993
Arọ́pòYiannakis Matsis
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1919-04-24)24 Oṣù Kẹrin 1919
Nicosia
Aláìsí(2013-11-15)Oṣù Kọkànlá 15, 2013
Nicosia
Ọmọorílẹ̀-èdèGreek Cypriot
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic Rally (Demokratikos Synagermos)
(Àwọn) olólùfẹ́Eirini Kliridou (died 6 June 2007)
Alma materKing's College London
Signature

Glafcos Clerides tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹrin ọdún 1919, tí ó sìn kú lọ́jọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kọkànlá ọdún 2013 (24th April 1919-15th November 2013).[1] jẹ́ Ààrẹ orílẹ̀-èdè Kíprù tẹ́lẹ̀. Òun ni Ààrẹ karùn-ún orílẹ̀-èdè Cyprus, láti ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ́n oṣù kejì ọdún 1993 sí ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ́n oṣù kejì ọdún 2003 [2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]