Jump to content

Gloria Oloruntobi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gloria Oloruntobi
Ọjọ́ìbí6 Oṣù Kejì 1997 (1997-02-06) (ọmọ ọdún 27)
Orúkọ mírànMaraji
Iléẹ̀kọ́ gígaYunifásitì Covenant
Iṣẹ́Content creator, comedienne, skit maker

Gloria Oloruntobi (tí wọ́n bí ní Oṣù kejì ọjọ́ kẹfà, ọdún 1997), tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Maraji, jẹ́ Òṣèré Apanilẹ́rìn-ín Nàìjíríà.[1][2][3][4] Ó bẹ̀rẹ̀ ìgbẹ́sí ayé rẹ̀ pẹ̀lú vídíò lip sync àti kọ orin olórin .[5] Maraji ṣeré nínu àwọn vídíò apanilẹ́rìn-ín kékeré àti lo àwọn ẹ̀ka-èdè àti ohùn oríṣiríṣi láti bá àwọn ẹ̀dá tó kópa lọ.[6][7]

Maraji jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Ẹdó. Ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ pẹ̀lú ẹ̀kọ́ ibáṣepọ̀ láàárín àwọn ìlú (international relations) láti Fáṣítì Covenant ní ọdún 2017.[8][9]

Maraji wà ní vídíò orin Falz's "Something Light" àti Yemi Alade's "Single and Searching" ".[10][11]


Àwọn oyè tó gbà àti àwọn ibi tí wọ́n pẹ̀ ẹ́ sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n pé Maraji fún Oyè eré apanilẹ́rìn-ín ni ọdún 2017 àti ọdún 2018 tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ The Future Awards Africa.[12][13][14] Wọ́n pẹ̀ ẹ́ fún Eré Apanilẹ́rìn-ín ní ọdún 2018 fún City People Music Awards.[15]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Meet the Nigerian creative who turned social media to her audience". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-13. Archived from the original on 2020-02-11. Retrieved 2020-03-30. 
  2. Nwosu, I. K. (2018-09-11). "Get to Know Comedian/Content Creator Gloria Oloruntobi (Maraji) on #The25Series". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-30. 
  3. "Maraji Says She Collects An Average Of N500,000 Per Skit And Nigerians Are Not Having It". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-09. Archived from the original on 2018-10-11. Retrieved 2020-03-30. 
  4. "YNaija presents: The 100 most influential Nigerians In Film in 2019 » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-11-01. Retrieved 2020-03-30. 
  5. "The Future Awards Africa Prize for Comedy". The Future Awards Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-02. Retrieved 2020-03-30. 
  6. "Top 10 people social media blew up". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-12-08. Retrieved 2020-03-30. 
  7. "Celebrities who became famous through Instagram - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com. Retrieved 2020-03-30. 
  8. "The Business Of 60 Second Skits: How Your Favourite Comedians Are Cashing Out On Instagram". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-16. Retrieved 2020-03-30. 
  9. "See Who Made Top 25 Under-30 Nigerian Superstars - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com. Retrieved 2020-03-30. 
  10. Reporter (2018-10-06). "20 Top Instagram Comedians Making Waves Online". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-30. 
  11. "10 Nigerian comedians who became popular on Instagram - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com. Retrieved 2020-03-30. 
  12. "#NigeriasNewTribe: The Future Awards Africa unveils nominees for 2017 edition". The Future Awards Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-11-24. Retrieved 2020-03-30. 
  13. "Burna Boy, Adesua Etomi, Maraji, others make 2018 The Future Awards nominee list". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-03. Retrieved 2020-03-30. 
  14. "The Future Awards Africa 2018 Nominees List". guardian.ng. Archived from the original on 2018-12-27. Retrieved 2020-03-30. 
  15. Pomaa, Precious (2019-03-19). "Meet 10 Guys Who Made Their 1st Million From INSTAGRAM". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-30.