Glory Alozie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Glory Alozie
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kejìlá 1977 (1977-12-30) (ọmọ ọdún 46)
Amator, Abia State, Nigeria

Gloria “Glory” Alozie Oluchi (tí wọ́n bí ní 30 December 1977) fìgbà kan jẹ́ eléré-ìdárayá tó máa ń kópá nínú eré-sísá.[1] Wọ́n bí i sí orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà, ó sì máa ń ṣojú orílẹ̀-èdè rẹ̀ àti ìlú Spain

Nígbà tó kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ ìkópa rẹ̀ nínú ìdíje ní ọdún 1996, ó di ẹni tó ní àṣeyọrí ńlá nínú iṣẹ́ tóyàn láàyò yìí. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò fìgbà kan jáwé olúborí nínú ìdíje àgbáyé rí, àmọ́ ó ti fìgbà márùn-ún gbé ipò kejì. Látàri ṣíṣe aṣojú fún Nàìjíríà, ó di ajáwé olúborí nínú àwọn ìdíje Africa ní ẹ̀ẹ̀mejì.[2]

Ìkópa rẹ̀ tó dára jù[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Event Time Date Venue
100 m 10.90 6 May 1999 La Laguna, Spain
200 m 23.09 14 July 2001 La Laguna, Spain
100 m hurdles 12.44 8 August 1998 Monaco

Ìkópa rẹ̀ nínú ìdíje àgbáyé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aṣojú fún Nàìjíríà Nàìjíríà
1995 African Junior Championships Bouaké, Ivory Coast 2nd 100 m hurdles 14.21
1996 World Junior Championships Sydney, Australia 2nd 100 m hurdles 13.30 (wind: +0.7 m/s)
African Championships Yaoundé, Cameroon 1st 100 m hurdles 13.62
1998 Grand Prix Final Moscow, Russia 3rd 100 m hurdles 12.72
African Championships Dakar, Senegal 1st 100 m hurdles 12.77
1999 World Indoor Championships Maebashi, Japan 2nd 60 m hurdles 7.87
World Championships Sevilla, Spain 2nd 100 m hurdles 12.44
2000 Olympic Games Sydney, Australia 2nd 100 m hurdles 12.68
Grand Prix Final Doha, Qatar 2nd 100 m hurdles 12.94
Aṣojú fún  Spéìn
2002 World Cup Madrid, Spain 3rd 100 m hurdles 12.95
4th 100 m 11.28
European Championships Munich, Germany 1st 100 m hurdles 12.73
4th 100 m 11.32
Grand Prix Final Paris, France 4th 100 m hurdles 12.65
2003 World Indoor Championships Birmingham, United Kingdom 2nd 60 m hurdles 7.90
European Indoor Cup Leipzig, Germany 1st 60 m hurdles 7.94
World Athletics Final Monaco 2nd 100 m hurdles 12.66
World Championships Paris Saint-Denis, France 4th 100 m hurdles 12.75
European Cup Florence, Italy 3rd 100 m 11.29
1st 100 m hurdles 12.86
2004 European Indoor Cup Leipzig, Germany 2nd 60 m hurdles 7.99
World Athletics Final Monaco 4th 100 m hurdles 12.69
2005 European Indoor Championships Madrid, Spain 4th 60 m hurdles 8.00
World Athletics Final Monaco 5th 100 m hurdles 12.76
European Cup First League (A) Gävle, Sweden 2nd 100 m hurdles 13.18
1st 100 m 11.53
Mediterranean Games Almería, Spain 1st 100 m hurdles 12.90
2006 World Indoor Championships Moscow, Russia 2nd 60 m hurdles 7.86
European Championships Gothenburg, Sweden 4th 100 m hurdles 12.86
2009 Mediterranean Games Pescara, Italy 4th 100 m hurdles 13.42

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Glory Alozie Archived 5 December 2013 at the Wayback Machine.. Sports Reference. Retrieved on 2014-01-12.
  2. Minshull, Phil (1998). Alozie after further glory on African soil Archived 19 August 2012 at the Wayback Machine.. IAAF. Retrieved on 2014-01-12.