Go Soeda
Ìrísí
Go Soeda je agba tenis, ọmọkùnrin orílẹ̀ èdè Japan. Ó bẹ̀rẹ̀ tennis gbígbá ní ọmọ ọdún mẹrin. Ó di ògbóǹtarigí ní ọdún 2013.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |