Godwin Babátúnde Kofi Akran
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Godwin Babatunde Kofi Akran)
Godwin Babatunde Kofi Akran (a bí Ọba Akran ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1936) lọ sí Salvation Army School, Kakawa, Lagos láàrin 1946 sí 1947, Methodist School, Badagry àti Methodist Teachers Training College, Ìfàkì-Èkìtì láàrin 1956 sí 1957. Ó lọ sí International Press Institute, University of East Africa, Nairobi, Kenya ní 1977. Ó di reporter fún West African Plot ní 1961, News Editor, New Nigerian Newspapers 1975-1977. Ó di Ọba ìlú Badagry gẹ́gẹ́ bíi De Whenọ Ahọlu Mẹnu Toyi 1 ní ọdún 1977.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |