Grace Asantewaa
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 5 Oṣù Kejìlá 2000 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Ghana | ||
Ìga | 1.59m | ||
Playing position | Defender | ||
Club information | |||
Current club | Real Betis Féminas | ||
Number | 15 | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
–2019 | Ampem Darkoa Ladies | ||
2019–2021 | EdF Logroño | 45 | (4) |
2021– | Real Betis Féminas | 6 | (1) |
National team‡ | |||
2018 | Ghana women's national football team | 4 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 2 February 2020. † Appearances (Goals). |
Grace Asantewaa jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghanan ti a bini 5, óṣu December ni ọdun 2000. Agbabọọlu naa ṣere fun Real Betis gẹgẹbi defender[1].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Grace kopa ninu Nations Cup awọn obinrin ilẹ afirica ti ọdun 2018[2].