Grace Asare
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 12 Oṣù Kẹ̀wá 1989 | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Reformers Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Grace Asare jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ gbana ti a bini 12, óṣu October ni ọdun 1989. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin Reformers gẹgẹbi defender[1][2].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Grace kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ti ọdun 2014[3].