Greg Grunberg
Appearance
Greg Grunberg | |
---|---|
Grunberg ní Phoenix Comic Fest ní ọdún 2018 | |
Ọjọ́ìbí | Gregory Phillip Grunberg 11 Oṣù Keje 1966 Los Angeles, California |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 1990–present |
Olólùfẹ́ | Àdàkọ:Married |
Àwọn ọmọ | 3 |
Gregory Phillip Grunberg (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù keje ọdún 1966) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Eric Weiss nínú eré ABC tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Alias, Matt Parkman nínú eré NBC tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Heroes, Temmin "Snap" Wexley nínú Star Wars: The Force Awakens àti Star Wars: The Rise of Skywalker, àti Phil nínú A Star Is Born. Ó farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré tí J. J. Abrams, ẹni tí ó jẹ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀ dárí bi àpẹẹrẹ, Felicity nínú Sean Blumberg. Ó tún ṣeré nínú eré Showtime tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Masters of Sex.
Ìpìlẹ̀ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Grunberg ní ìlú Los Angeles, California, sínú ìdílé Sandy (née Klein) àti Gerry Grunberg[1][2] wọ́n sì tọ dàgbà ní ìlànà Júù.[3] Ó lọ ilé-ìwé University High School ní West Los Angeles.[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Greg Grunberg Biography Archived May 22, 2011, at the Wayback Machine., Yahoo!. Retrieved March 2, 2016.
- ↑ Greg Grunberg profile, nndb.com. Retrieved November 2, 2013.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedJewishFederations
- ↑ University High School 1984 yearbook, Uni Hi Education Foundation. Retrieved November 7, 2021.