Gregor Mendel

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gregor Johann Mendel marulo
Ìbí(1822-07-20)Oṣù Keje 20, 1822
Heinzendorf bei Odrau, Silesia, Austrian Empire
AláìsíJanuary 6, 1884(1884-01-06) (ọmọ ọdún 61)
Brno, Moravia, Austria-Hungary
Ọmọ orílẹ̀-èdèAustria-Hungary
Ẹ̀yàGerman
PápáGenetics
Ilé-ẹ̀kọ́Abbey of St. Thomas in Brno
Ibi ẹ̀kọ́University of Vienna
Ó gbajúmọ̀ fúnDiscovering genetics
Religious stanceRoman Catholic

Gregor Johann Mendel (July 20, 1822[1] – January 6, 1884) je ojise olorun ati onimosayensi ara Austria, to gbajumo leyin iku re gege eni pataki ninu sayensi tuntun genetics nitori agbeka ijogun iru maruloawon iwa kan pato ninu ogbin ewa popondo. Mendel fihan pe ijogun awon iwa wonyi untele awon ofin kan pato, ti won gba oruko re lojowaju. Bi ise Mendel yi se se pataki to ko je didamo ki o to di ibere orundun 20k. Itunwari alominira awon ofin wonyi ni won se ifilole sayensi odeoni ton unje genetiki.[2]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. July 20 is his birthday; often mentioned is July 22, the date of his baptism. Biography of Mendel at the Mendel Museum Archived 2014-10-21 at the Wayback Machine.
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named pb