Grey Dawn (fíìmù)
Appearance
Grey Dawn | |
---|---|
Adarí | Shirley Frimpong-Manso |
Olùgbékalẹ̀ | Ken Attoh Shirley Frimpong-Manso |
Òǹkọ̀wé | Shirley Frimpong-Manso |
Àwọn òṣèré |
|
Orin | Ivan Ayitey |
Ìyàwòrán sinimá | Sadiq Al-Hassan |
Olóòtú | Shirley Frimpong-Manso |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Sparrow Productions |
Olùpín |
|
Déètì àgbéjáde |
|
Orílẹ̀-èdè | Ghana Nigeria |
Èdè | English |
Grey Dawn jẹ́ fíìmù ilẹ̀ Ghana àti Nàìjíríà tí ó jáde ní ọdún 2015, èyí tí Shirley Frimpong-Manso jẹ́ olùdarí rẹ̀. Àwọn òṣèré bíi Bimbo Manuel, Funlola Aofiyebi-Raimi, Sika Osei àti Marlon Mave ló kópa nínú fíìmù náà.[1][2][3]
Àwọn akópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Bimbo Manuel bíi Minister
- Funlola Aofiyebi-Raimi bíi
- Sika Osei bíi
- Marlon Mave bíi Jacques
- Kofi Middleton Mends bíi Kweku Yanka
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Movie Trailer: Grey Dawn (Nollywood)". Afrofresh. 20 January 2015. Archived from the original on 31 July 2017. Retrieved 24 March 2015.
- ↑ "Shirley Frimpong-Manso To Release New Movie, "Grey Dawn." Watch Trailer". True Nollywood Stories. Archived from the original on 23 April 2015. Retrieved 24 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Full house at Shirley Frimpong-Manso's 'Grey Dawn' premiere (Photos)". Ghana Web. 15 February 2015. Retrieved 24 March 2015.