Guru Maharaj Ji
Ìrísí
Guru Maharaj Ji tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Mohammed Ajírọ́batán jẹ́ olùdarí ilé ìjọsìn kan tó fìkàlẹ̀ sí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó júwe ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí "Ọ̀gá Ẹ̀dá-Àlàyè tó mọ́ jùlọ", ó sì tún pe ara rẹ̀ ní "Jésù dúdú". Ó ní òun lágbára láti ṣe ìwòsàn àti gbogbo nǹkan tó bá ń da ènìyàn láàmú. [1] [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Udodiong, Inemesit (2018-01-25). "All you need to know about “Black Jesus”". Pulse Nigeria. Retrieved 2019-11-23.
- ↑ "Avoiding Sat Guru Maharaj Ji’s philosophy, by Ahmed Suleiman". The Eagle Online (in Èdè Bosnia). 2018-04-22. Retrieved 2019-11-23.