Hájì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mosalasi Masjid al-Haram ti won ko sori kabaa ni Mekka

Haji ni irinajo lo si Mẹ́kkà. Lọwọlọwọ ọ jẹ irinajo to tobijulo, o si je okan ninu Opo marun Islamu ni pato ikarun. O se dandan fun eni to je mùsùlùmí lati lo si Haji lekan ni igbesiaye won.
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]