Jump to content

Hadiza Aliyu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
HADIZA ALIYU GABON
Ọjọ́ìbíHadiza Aliyu
1 Oṣù Kẹfà 1989 (1989-06-01) (ọmọ ọdún 35)
Libreville, Gabon
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actress, film maker
Ìgbà iṣẹ́2009–present
Notable credit(s)Best known for her appearance in Ali Yaga Ali
AwardsSee below
Websitehadizaaliyu.com

Hadiza Aliyu (bíi ni ọjọ́ kìíní oṣù kẹfà ọdún 1989)[1] jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú fún ilé iṣẹ́ MTN Nigeria àti Indomie noodles. Ó gbà ẹ̀bùn òṣèré tó dára jù lọ ní ọdún 2013 láti ọ̀dọ̀ Nollywood Awards, ó sì gba ẹ̀bùn láti ọ̀dọ̀ Kannywood àti MTN ni ọdún 2014.

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ aiyé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí sì ìlú Libreville ni orílẹ̀ èdè Republic of Gabon.[2] Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀ Gabon ṣùgbọ́n ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìpínlè Adamawa ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà[3][4].

Hadiza dara pọ̀ mọ́ Kannywood lẹ́yìn ìgbà tí ó padà sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[5] Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ni ọdún 2009 nínú eré Artabu[6] Ó darapọ̀ mọ́ Nollywood ni ọdún 2017[7], ó sì kópa nínú eré Lagos Real Fake Life.[8][9] Ní oṣù kejìlá, ọdún 2018, ilé iṣẹ́ NASCON Allied Plc, fi ṣe asoju wọn.[10][11] [12] Ní ọdún 2016, ó dá egbe HAG foundation kalẹ̀.[13] Ẹgbẹ́ naa si wa láti pèsè iranlọwọ ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́, oúnjẹ àti ìlera tí ó péye fún àwọn aláìní.[14]

Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdun Akọle Ipa ti o ko Genre
Daina Kuka[15] Actress Drama
Farar Saka Actress Drama
Fataken Dare Actress Drama
KoloBabban ZaureBabban Zaure Actress Drama
Mukaddari Actress Drama
Sakayya Actress Drama
Umarnin Uwa Actress Drama
Ziyadat Actress Drama
2009 Artabu Actress Drama
2010 WasilaBabban ZaureBabban Zaure Actress Drama
2010 Umarnin Uwa Actress Drama
2012 Aisha Humaira Actress Drama
2012 'Yar Maye Actress Drama
2012 Badi Ba Rai Actress Drama
2012 Akirizzaman Actress Drama
2012 Dare Daya Actress Drama
2012 Wata Tafi Wata Actress Drama
2013 Da Kai Zan Gana Actress Drama
2013 Haske Actress Drama
2013 Ban Sani Ba Actress Drama
2014 Mai Dalilin Aure Actress Drama
2014 Daga Ni Sai Ke Actress Drama
2014 Ali Yaga Ali Actress Drama
2014 Basaja Actress Drama
2014 Uba Da 'Da Actress Drama
2014 Indon Kauye Actress Comedy/Drama
2014 Ba'asi Actress Drama
2014 Jarumta Actress Drama
2017 Gida da waje Actress Drama
2017 Ciki Da Raino Actress Comedy/Drama
2019 Hawwa Kulu Actress Drama
2019 Wakili Actress Drama
2019 Dan Birnin Actress Drama
2019 Gidan Badamasi Actress Comedy/Drama


Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Hadiza Aliyu". 
  2. All Africa. "Nigeria: I Had to Learn Hausa to Feature in Kannywood - Hadiza Gabon". Amina Alhassan and Mulikat Mukaila. Retrieved 28 December 2013. 
  3. "I want to settle down – Gabon - Blueprint". Archived from the original on 2015-04-02. Retrieved 2015-03-10.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Gabon Official". Archived from the original on 2015-03-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Husseini, Shuaibu (12 November 2016). "Gold for Kannywood’s shinning star, Hadiza Gabon, from Queensland". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 24 October 2019. Retrieved 24 October 2019. 
  6. "Hadiza Gabon - HausaFilms.tv". 
  7. Lere, Muhammad (21 September 2017). "Kannywood: Hadiza Gabon features in first Nollywood movie - Premium Times Nigeria". Premiumtimenews. Retrieved 24 October 2019. 
  8. Elites, The (21 September 2017). "Famous Kannywood Actress Hadiza Aliyu Gabon, Debuts In Nollywood Movie". The Elites Nigeria. Retrieved 24 October 2019. 
  9. "The trailer for Mike Ezuruonye's new movie ‘Lagos Real Fake Life’ isn't quite there yet » YNaija". YNaija. 10 October 2018. Retrieved 24 October 2019. 
  10. "NASCON launches New Dangote Classic Seasoning Cubes". NASCON launches New Dangote Classic Seasoning Cubes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 
  11. "NASCON introduces Dangote classic seasoning into Kano market". Businessday NG. 17 December 2018. https://businessday.ng/companies/article/nascon-introduces-dangote-classic-seasoning-into-kano-market. 
  12. "Brand Ambassador Market Tour". NASCON. 16 July 2019. Archived from the original on 10 August 2020. Retrieved 12 October 2020. 
  13. "HAG Foundation - Committed to Serving Humanity". HAG Foundation. Archived from the original on 2 February 2017. Retrieved 22 January 2017. 
  14. "Hadiza Gabon enlivens IDP camp". Daily Trust. Ibrahim Musa Giginyu. Retrieved 19 March 2016. 
  15. "Gabon Official". Archived from the original on 2015-03-24.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)