Jump to content

Haile Gebrselassie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Haile Gebrselassie
Gebrselassie at the 2010 Dubai Marathon
Òrọ̀ ẹni
Height1.65 m (5 ft 5 in)[1]
Weight56 kg (123 lb)[1]
Sport
Orílẹ̀-èdè Ethiopia
RetiredNovember 7, 2010

Haile Gebrselassie (Àdàkọ:Lang-am, haylē gebre silassē; ojoibi April 18, 1973) je ara Ethiopia asareidaraya ona jijina ati isare ojuona. O gba eso wura Olympiki meji fun 10,000 metres ati ife-eye Idije Agbaye merin fun ijinna kanna. O bori ni Berlin Marathon lemerin leralera ati Dubai Marathon lemeta leralera. Bakanna, o tun gba ipo kinni ni emerin fun awon idije inuule, ohun si tun ni Adijekinni Marathon Idaji Agbaye 2001. Ni Oṣu kọkanla ọdun 2021, Haile Gebreselassie wa ni iwaju ogun ni Etiopia lodi si awọn ọlọtẹ ti Tigray.