Halima Abubakar
Halima Abubakar | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 12 Oṣù Kẹfà 1985 Kánò, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Bayero University |
Iṣẹ́ | Òṣèrébìnrin[1], CEO, Modehouse Entertainment |
Awards | Best Actress, 2011 Afro Hollywood Awards |
Halima Abubakar ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹfà ọdún 1985. [2] jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [3][4][5]Ní ọdún 2011, ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Afro Hollywood Best Actress award.[6][7]
Ìgbé ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Abubakar ní Ìpínlẹ̀ Kánò , àmọ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Kogí ni.[8] ó sì tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bérẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Kano. [9] Ó tún kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìmọ̀ àkọ́kọ́ ní ú ìmọ̀ Sociology ní ilé-ẹ̀kọ́ Bayero University ní Ìpínlẹ̀ Kano. Abubakar fidí rẹ̀ múlẹ̀ wípé òun ṣì ní ìbálé ní oṣù kẹwàá ọdún 2018.[10]
Ní inú oṣù Kẹ́rin ọdún 2020, ó kéde pé òun bímọ ọkùnrin[11]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré tíátà ní ọdún 2001, níbi tí ó ti kópa nínú eré Rejected. Ó kópa bí olú-èdá ìtàn nínú eré Gangster Paradise. 9un ló dá iṣẹ́ Modehouse Entertainment, tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìgbórin jáde.[12]
Àwọn Fíímù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Slip of Fate
- Tears of a Child
- Secret Shadows
- Gangster Paradise
- Area Mama
- Men in Love
- Rejected
- Love Castle
- Entrapped
- Dangerous Ivy
- Return of White Hunters
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Halima Abubakar quits acting over undisclosed ailment". Vanguard News. October 19, 2022. Retrieved November 26, 2022.
- ↑ "In Pictures: Halima Abubakar Birthday Shoot". jaguda.com. Archived from the original on 29 February 2016. Retrieved 7 October 2014.
- ↑ "I can embarrass you if you get randy with me – Halima Abubakar". vanguardngr.com. Retrieved 7 October 2014.
- ↑ "Halima Abubakar explodes: Why I fought Tonto Dikeh". modernghana.com. Retrieved 7 October 2014.
- ↑ Jonathan, Oladayo (October 18, 2022). "Sex Scandal: Halima Abubakar quits acting as Apostle Suleman files charges". Premium Times Nigeria. Retrieved November 26, 2022.
- ↑ "2face Idibia and Annie Maculay Lighten Up Halima Abubakar Birthday". gistmania.com. Retrieved 7 October 2014.
- ↑ "Actress Halima Abubakar’s cancer support strategy … good or bad?". vanguardngr.com. Retrieved 7 October 2014.
- ↑ "Day I Cried Over My Boyfriend –Actress Halima Abubakar". Daily Sun Newspaper. primenewsnigeria.com. Archived from the original on 12 October 2014. Retrieved 7 October 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "My first…Halima Abubakar". The Punch. Archived from the original on 12 October 2014. https://web.archive.org/web/20141012201847/http://www.punchng.com/entertainment/weekendstarter/my-first-halima-abubakar/.
- ↑ http://www.vanguardngr.com/2018/10/i-cant-wait-to-experience-sex-halima-abubakar/
- ↑ Clifford, Igbo. "Halima Abubakar Biography, Age, Early Life, Family, Education, Career, Net Worth And More". Information Guide Africa. Retrieved 2020-04-07.
- ↑ "Halima Abubakar turns music-entrepreneur". punchng.com. Archived from the original on 12 October 2014. Retrieved 7 October 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Iroko Tv Archived 2022-11-26 at the Wayback Machine.
- Pages with citations using unsupported parameters
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókí tó jẹ́ àfikún PearBOT 5
- Webarchive template wayback links
- People from Kano State
- 21st-century Nigerian actresses
- Bayero University Kano alumni
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1985