Halimatu Àyìnde
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Halimatu Ibrahim Ayinde | ||
Ọjọ́ ìbí | 16 Oṣù Kàrún 1995 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Kaduna, Nigeria | ||
Ìga | 1.65m | ||
Playing position | Midfielder | ||
Club information | |||
Current club | Eskilstuna United DFF | ||
Number | 18 | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Delta Queens | |||
2015–2016 | Western New York Flash | 9 | (1) |
2016 | FC Minsk (women) | 5 | (4) |
2018 | Asarums IF FK | 22 | (4) |
2019- | Eskilstuna United DFF | 38 | (0) |
National team‡ | |||
2010–2012 | Nigeria women's national under-17 football team | 6 | (4) |
2014 | Nigeria women's national under-20 football team | 6 | (0) |
2015– | Nigeria women's national football team | 12 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 01:45, 20 June 2019 (UTC). † Appearances (Goals). |
Haimatu Àyinde jẹ àkọṣẹmọṣẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 16, óṣu May ni ọdun 1995. Arabinrin naa ṣere fun Eskilstuna United DFF ati team awọn obinrin lapapọ gẹgẹbi Midfielder. Arabinrin naa tifi igba kan ṣere fun Western New York ni United States ati Delta Queens ni órilẹ ede naigiria[1][2][3][4].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Halimatu yege ninu ere idije awọn obinrin ilẹ Afirica to waye ni ọdun 2014.Elere naa kopa ninu 2015 Cup FIFA awọn obinrin agabaye nibi ti o ti jẹ aṣoju fun team apapọ orilẹ ede naigiria[5].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.playmakerstats.com/player.php?id=417507
- ↑ https://ng.soccerway.com/players/halimatu-ayinde/150702/
- ↑ https://fbref.com/en/players/e29e3055/Halimatu-Ayinde
- ↑ https://www.eurosport.co.uk/football/halimatu-ayinde_prs332036/person.shtml
- ↑ https://m.football-lineups.com/footballer/102031/Womens-World-Cup-Canada-2015/Nigeria