Hamdya Abass
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | ọjọ́ kinni oṣù Kẹjọ ọdún 1982 | ||
Playing position | Asọ́lé | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Ghatel Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana | 7 | (0) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Hamdya Abass tí a bí ní ọjọ́ kinni oṣù Kẹjọ ọdún 1982 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin àgbáyé ti ilẹ̀ Ghana kan tí ó dúró gẹ́gẹ́ bí asọ́lé . Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti ẹgbẹ́ àwọn obìnrin agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède Ghana . Ó wà lára àwọn tí ó kópa pẹ̀lú 2007 FIFA Women's World Cup . Nípa ikọ̀ ẹgbẹ́ ó ṣeré fún Ghatel Ladies ní Ghana. [1]
Wo eléèyí ná
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Àkójọ àwọn agbábọ́ọ̀lù àgbáyé ti àwọn obìnrin Ghana
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdàkọ:Ghana squad 2007 FIFA Women's World CupÀdàkọ:Ghana squad 2007 FIFA Women's World CupÀdàkọ:Authority control