Hana El Zahed

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Hana El Zahed
Ọjọ́ìbí5 Oṣù Kínní 1994 (1994-01-05) (ọmọ ọdún 30)
Cairo, Egypt
Orílẹ̀-èdèEgyptian
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2003-present

Hana El Zahed (tí wọ́n bí ní 5 Oṣù Kínní, Ọdún 1994) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Egypt.

Ìtàn ìgbésí ayé rẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

El Zahed a bí ni ọdún 1994. O bẹrẹ èrè ori itage nínú sinima agbelewo Al Meshakhsaty ni ọdún 2003. Ni ọdún 2009,o kópa gẹgẹ bí ọmọ ọmọ òṣèré Mohamed Sobhi nínú ere Telifisonu Yawmeyat Wanees we Ahfadoh. El Zahed fi ìgbé dèké sí ere ori itage .[1] o ṣe àpèjúwe ìbéèrè iṣẹ eré rẹ gẹgẹ bí èyí tí kò ní ètò, sùgbón ni pa sábà bí .[2]

El Zahed béèrè iṣẹ rẹ pada gẹgẹ bí o ni tiata nínú èrè Jimmy's Plan ni ọdún 2014. Nínú ọdún na , a fi se ọkàn lára àwọn eléré nínú Tamer Hosny's TV series Farq Tawqit.[3] In 2015, El Zahed ni ipò nínú èrè Alf Leila wa Leila, Mawlana El-aasheq, and El Boyoot Asrar. Ni ọdún tó tẹlẹ, o kópa nínú Al Mizan.[1] ni oṣù kàrún ọdún 2017, El Zahed fi ara hàn nínú èrè Telifisonu Fel La La Land, ti a kò láti ọwọ́ Mustafa Saqr àti Olùdarí Ahmed el-Gendy. Ètò yí di gbajugbaja ni ile Egypt's ti a wo ju lori ayé lujara .[4] o sí tu kópa nínú Ahlan Ramadan.[3] ni ọdún2018, El Zahed se àfihàn nínú Sons of Adam.[5]

Ni oṣù Kejì ọdún 2019, El Zahed se ere gẹgẹ bí Gamila nínú Love Story. O fi ara hàn El wad sayed el shahat nínú osù karún, pẹlu a fẹ sónà Ahmed Fahmy.[6] El Zahed fé Fahmy ni ọjọ kọkànlá oṣù kẹsán ọdún 2019 ayẹyẹ tí ọ tóbi, pẹlu Mohamed Hamaki ti ọ kọrin .[7] ni ibi ijefaaji ìgbéyàwó, a gbé lọsí ilé ìwòsan nítorí àrùn inu rirun ni Singapore.[8] ni ọdún 2020, El Zahed fara hàn nínú èrè awada The Washing Machine pẹlú Mahmoud Hemida. Olùdarí èrè na ni Essam Abdel Hamid ti ọ fara hàn ní ọjọ ọlá place .[1] èrè Telifisonu ohun gba oríṣiríṣi ọrọ nitori COVID-19 pandemic.[9] ni oṣù keje ọdún 2020, awọn ọkunrin sọrọ ọ di sí ní ìlú Cairo.[10]

  1. 1.0 1.1 1.2 Sameh, Yara (6 October 2020). "Hannah El Zahed Stuns in New Instagram Photos". See News. Retrieved 19 November 2020. 
  2. "Hana El Zahed tells her career's story". Arabs Today. 19 February 2017. https://www.arabstoday.net/en/103/hana-el-zahed-tells-her-careers-story-150018. Retrieved 19 November 2020. 
  3. 3.0 3.1 Simon, Alexander (10 August 2017). ""Sada El-Balad" hosts actress Hana El-Zahed". Standard Republic. Archived from the original on 6 September 2017. https://web.archive.org/web/20170906061242/http://www.standardrepublic.com/2017/08/sada-el-balad-hosts-actress-hana-el-zahed/19469.htm. Retrieved 19 November 2020. 
  4. Al-Youm, Al-Masry (22 May 2017). "Women stars dominate Ramadan 2017 TV season". Egypt Independent. https://www.egyptindependent.com/ramadan-2017-women-stars/. Retrieved 19 November 2020. 
  5. "يوسف الشريف ينتظر «بنى آدم» فى عيد الأضحى" (in ar). الهيئة الوطنية للإعلام. 1 June 2018. Archived from the original on 18 February 2022. https://web.archive.org/web/20220218155521/https://www.maspero.eg/wps/portal/home/radio-and-tv-magazine/art/details/70ce48a7-bcb7-49c7-aabe-725a18551b29/. Retrieved 19 November 2020. 
  6. "Jealousy? A fẹ sónà rẹ binu lori àwòrán èrè Hana Al Zahed's". Al Bawaba. 22 January 2019. https://www.albawaba.com/entertainment/jealousy-hana-al-zaheds-fianc%C3%A9-angry-about-new-films-poster-1242346. Retrieved 19 November 2020. 
  7. Abusief, Fatma (12 September 2019). "Inside Ahmed Fahmy and Hana El Zahed's star-studded wedding". Emirates Woman. https://emirateswoman.com/ahmed-fahmy-hana-el-zahed-wedding/. Retrieved 19 November 2020. 
  8. "Terrifying! Hannah El Zahed Transferred to Hospital in Singapore During Honeymoon.. Is she Ok?". Al Bawaba. 23 September 2019. https://www.albawaba.com/entertainment/terrifying-hannah-el-zahed-transferred-hospital-singapore-duing-honeymoon-she-ok. Retrieved 19 November 2020. 
  9. "The heroes of the movie "The Washer" are under fire for a picture – Erm News". Eg24 News. 7 June 2020. https://www.eg24.news/2020/06/the-heroes-of-the-movie-the-washer-are-under-fire-for-a-picture-erm-news.html. Retrieved 19 November 2020. 
  10. Al Sherbini, Ramadan (10 July 2020). "Egyptian actress reports road harassment". Gulf News. https://gulfnews.com/world/mena/egyptian-actress-reports-road-harassment-1.72520021. Retrieved 19 November 2020.