Jump to content

Hank Johnson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Henry C. "Hank" Johnson Jr.
Member of the U.S. House of Representatives
from Georgia's 4th district
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
January 3, 2007
AsíwájúCynthia McKinney
Arọ́pòIncumbent
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí2 Oṣù Kẹ̀wá 1954 (1954-10-02) (ọmọ ọdún 70)
Washington, D.C.
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic
(Àwọn) olólùfẹ́Mereda Davis Johnson
ResidenceLithonia, Georgia
Alma materClark Atlanta University, Texas Southern University
OccupationAttorney

Henry C. "Hank" Johnson Jr. (ojoibi October 2, 1954) je oloselu ara Amerika ati Asoju Ile Asofin Amerika fun àgbègbè iléaṣòfin Georgia 4k, lati 2007. O je omo Egbe Demokratiki.