Harold Bloom
Appearance
Harold Bloom | |
---|---|
Iṣẹ́ | literary and cultural critic |
Literary movement | Romanticism, Aestheticism, Deconstruction |
Notable works | The Western Canon, The Anxiety of Influence |
Harold Bloom (July 11, 1930 si October 14, 2019) je olukowe omo ile Amerika.
O je aláríwisí lítírèso ile Amerika ti o je gbàjumò fun àséyorí re ni síse ítúnmo itan lítírèso àtí fun ísedà lítírèso.
Die nínù àwon íse re ti o je gbàjumò ni, The Anxiety of Influence (1973), The Western Canon (1994) and How to Read and Why (2000).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |