Harry Belafonte
Appearance
Harry Belafonte | |
---|---|
Belafonte at the 2011 Tribeca Film Festival Vanity Fair party | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Harold George Bellanfanti, Jr. |
Ọjọ́ìbí | 1 Oṣù Kẹta 1927 Harlem, New York, U.S. |
Irú orin | Calypso, vocal, folk |
Occupation(s) | Actor, activist, singer |
Years active | 1949–2003 |
Labels | RCA Victor CBS EMI Island |
Harold George "Harry" Belafonte, Jr. (March 1, 1927 - April 25, 2023) je akorin, osere ati ati alakitiyan awujo ara Amerika. O je pipe bi "Oba Orin Calypso" fun imugbajumo iru orin Caribbean kakiri aye ni ewadun 1950. Belafonte gbajumo fun kiko orin "The Banana Boat Song", pelu igbe-orin "Day-O." Kakiri ise re o je agbejero fun eto araalu ati ija omoniyan.