Jump to content

Hassan Oyeleke

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Hassan Oyeleke (ojoibi 1 October 1962) je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà ati olórí ilé ìgbìmò aṣofin kẹjọ ti o nsójú agbègbè Essa/Shawo/Igboidun ni ile igbimo asofin ìpínlè Kwara . [1] [2] [3]