Jump to content

Taiwo Hassan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Hassan Taiwo)

Taiwo Hassan tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ògògó ni a bí ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1959 (31-10-1959). Ó jẹ́ àgbà òṣèré, olóòtú, olùdarí eré orí ìtàgé àti Sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú Ìlaròó ní Ìpínlẹ̀ Ògùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2]

  1. Google 2016.
  2. "TAIWO HASSAN". NollyTrends. 1959-10-31. Archived from the original on 2019-09-21. Retrieved 2019-09-21. 

Àwọn ibùdó lori Interneti

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]