Jump to content

Hausawa Aminu Ghali

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́





Hausawa Aminu Ghali
je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà lati ìpínlè Kano. Ó sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin, tó ń ṣojú Gwale ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà. Odun 1999 ni won dibo fun un o si ṣíṣe titi di ọdún 2003 lábé ẹgbẹ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP). Jazuli Imam ni o tẹle e. [1] [2]