Hayden Panettiere
Ìrísí
Hayden Panettiere | |
---|---|
Panettiere ní Fan Expo Canada ní ọdún 2011 | |
Ọjọ́ìbí | Hayden Lesley Panettiere[1] 21 Oṣù Kẹjọ 1989 Palisades, New York, U.S.[2] |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1993–present |
Height | Àdàkọ:Infobox person/height |
Alábàálòpọ̀ | Wladimir Klitschko (2009–2011, 2013–2018) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Àwọn olùbátan | Jansen Panettiere (brother) |
Hayden Lesley Panettiere ( /ˌpænətiˈɛər/; tí a bí ní ọjọ́ kanlelogun oṣù kẹjọ ọdún 1989)[3] jẹ́ òṣèrébìnrin àti akọrin ọmọ orílẹ̀ èdè Amerika. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ́ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Claire Bennet nínú eré Heroes (2006–2010) àti gẹ́gẹ́ bi Juliette Barnes nínú eré Nashville (2012–2018), ó gba àmì ẹ̀yẹ méjì fún Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Series, Miniseries or Television Film.[4] Ó tún kópa nínú fíìmù Scream, òun ni ó kópa Kirby Reed nínú fíìmù náà.
Ó jẹ́ ọmọ bíbí Palisades, New York, ó kọ́kọ́ hàn lórí ẹ̀rọ ìmóhùn máwòrán nínú ìpolówó kan ní ọdún 1990 nígbà tí ó jẹ́ ọmọ oṣù mọ́kànlá. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré ní pẹrẹwu nígbà tí ó kó ipa Sarah Roberts nínú fíìmù One Life to Live láti ọdún 1994 sí ọdún 1997.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "BMI - Repertoire Search". repertoire.bmi.com. Archived from the original on February 28, 2018. Retrieved February 27, 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Hischak, Thomas S. (2011). Disney Voice Actors: A Biographical Dictionary. McFarland. p. 163. ISBN 978-0-786-48694-6. https://archive.org/details/disneyvoiceactor00thom.
- ↑ "Interview with Hayden Panettiere". Interviews. The Source for Youth Ministries. October 19, 2004. Archived from the original on June 26, 2013. Retrieved June 16, 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "70th Golden Globe Awards Nominations". Deadline Hollywood. December 13, 2012. Archived from the original on October 14, 2013. Retrieved February 1, 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)